Lákõökö iśë yìí yóò là wá lóye yóò sí tún fún wa ní ìmõ kún ìmõ nítorí ôgbön kò pín sí ibìkan bí a bá śe ń wádìí nýkan náà ni ìmõ wa yóò máa gbòró sí nítorí ôgbön kò pín síbí kan. Yàtõ sí èyí iśë yìí yóò mú ìmõ êkö têsíwàjú nítorí pé àwôn òýkõwé ti śiśë gbënàgbënà, tiwa ni láti śiśë gbënugbënu. Èyí yóò ran àwôn òýkõwé àti aśàtúpalê löwö láti ni ìmõ kún ìmõ.
TABLE OF CONTENT
Title Page……………………………………………………………………i
Certification…………………………………………………..………….,....ii
Dedication…………………………………………………..…………..…..iii
Acknowledgment………..……………………………………….……........iv
List of Symbols and Abbreviations ……………………………....................v
Tables of Content...………………………………..………………………vii
CHAPTER ONE
Introduction
1.0Introduction…………….……………………………..………………1
1.1Historical Background of Migili People…..……………………….....1
1.2Socio-cultural Profile of Migili………………………….……….…...2
1.2.1 Religion……………..……………………………………….………...3
1.2.2 Occupation…………………………………………………………….3
1.2.3 Marriage and Burial rite………………………………..……………..3
1.2.4 Mode of Dressing………………………..………………………...…..5
1.2.5 Festival……..…………………………………………………………5
1.3Genetic Classification of Migili Language………………...................6
1.4Scope and Organisation of Migili Language…………………………8
4.1.2.2 Direct Object NP Focusing………………..…….………….……..97
4.1.3 Negation and Question Formation……………………………….101
4.1.3.1 Yes/No Questions………………………..…………………….…101
4.1.3.2 WH Questions………………………….………………………..104
4.1.4 Negation and Reflexivization…………………………………..…107
CHAPTER FIVE
Summary and Conclusion
5.0 Introduction……………………………………………………….112
5.1 Summary………………………………………………………….112
5.2 Observation………………….……………….………………..….113
5.3 Conclusion……………………………………………………..…113
5.4 References……………………….………………………………..114
ÌPILÊŚÊ IŚË ÌWÁDÌÍ
ÌFÁÀRÀ
Kò sí àníàní pé ìlò èdè śe pàtàkì nínú iśë ônà aláwòmö lítíréśõ. Tí a bá sô pé iśë ônà lítíréśõ kan dùn, èdè inú rê ló dùn. a wá le sô pé améwìdùn, amútàndùn ni èdè, amáyédùn sì ni pêlú. Fún ìdí èyí, kì í śe àìrí-nýkan-śe bí a bá sô pé a fë śàyêwò ìlò èdè inú iśë lítíréśõ kan.
Ohun to jç wá lógún nínú iśë ìwádìí yìí ni láti śe àyêwò fínnífínni, õnà tí Olúyëmisí Adébõwálé gbà lo èdè nínú ewì Ìgbà Lonígbàákà. Èyí ni yóò ràn wá löwö láti śe ìgbéléwõn ààyè òýkõwé náà láàrín àwôn òýkõwé ewì alákôsílê Yorùbá yòókù. Bákan náà, a ò le sô ipa tí iśë òýkõwé náà le kó nínú ìdàgbàsókè ewì àpilêkô Yorùbá ní pàtàkì àti àwùjô Yorùbá lápapõ.
ÈRÈDÍ IŚË ÌWÁDÌÍ
Yorùbá bõ wön ní êsê kan kì í dédé śe. Bí a śe mõ pé kò sí ènìyàn kan tí yóò dáwö lé iśë kan tí kò ní ní ìdí kan pàtó tí ó fi śiśë náà. Onírúurú nýkan ló mú wa lökàn tí a fi śiśë àpilêkô yìí.
Lákõökö a ti ní ìmõ lö lökàn-ò-jõkan lórí bí a śe le śe ìtúpalê iśë aláwòmö lítíréśõ kan. Fún ìdí èyí, a ní láti śàmúlò ìmõ náà nítorí pé nýkan tí a bá mõ tí a kò lò bí i pé a kò mõ ön ni.
Bákan náà ni a śe iśë yìí láti fa onírúurú àkíyèsí yô yálà àléébù tàbí ìwúlò lórí ìwé Ìgbà Lonígbàákà tí iśë yìí dálé àwôn àkíyèsí wõnyìí yóò wúlò fún wa àti fún àwùjô lápapõ. Yàtõ sí èyí, nýkan mìíràn tó tún mú wa dáwölë iśë ìwádìí yìí ni pé ìwé Ìgbà Lonígbàákà jë ìwé tuntun láwùjô, kò sí tí ì sí çnikëni tó ti śe iśë ìtúpalê ìwé náà bí i ti àwôn ìwé yókù tó jë pé ojojúmö ni àwôn onímõ lölökan-ò-jõkan ń śiśë lé wôn lórí. A wòye pé ó ye kí omi tuntun rú kí çja tuntun sí wôbê. Èyí yóò mú kí a le śàmúlò ìmõ wa nípa ìtúpalê iśë aláwòmö lítíréśõ fínnífínní lai jë pé a wo nýkan tí àwôn onímõ ti śe lórí iśë náà. Ìdí mìíràn tí a fi śiśë yìí ni pé òýkõwé jë obìnrin iśë yìí yóò mú kí iśë àwôn obìnrin náà bêrê sí ní di ìlú mõöká.
This research is aimed at discussing the general overview of Noun Phrase in Migili language. This research work is divided into five chapters. Chapter one which is the introductory part include: the historical background, socio-cultural profile, the scope and organization of study as well as the theoretical framework, the data collection method... Continue Reading
ASPECTS OF MIGILI MORPHOLOGY CHAPTER ONE 1.0 GENERAL INTRODUCTION Language is the universal fabric that holds every individual of a community together. An instrument, used by man for communication within his environment, without which there would be no meaningful relationship between the human world. Language... Continue Reading
CHAPTER ONE INTRODUCTION 1.0 General Background of the Study Language is the fabrics that ties every member of the society together, which serves as an instrument used by man for specific and distinguishable purposes. Indeed, the focus of this research is to shed light on how verb phrases are formed in Migili language. Therefore, the first... Continue Reading
This research is aimed at discussing the general overview of verb phrase in Migili language. This research work is divided into five chapters which are relevant aspects of the theory of syntax. TABLE OF CONTENTS Title Page i Certification ii Dedication iii Acknowledgements iv Table of Contents vi CHAPTER ONE: INTRODUCTION 1.0 General Background of... Continue Reading
CHAPTER ONE INTRODUCTION 1.0. General Background This chapter introduces the language of study, the people speaking the language and their geographical location. It introduces us to the background of the speakers of the... Continue Reading
This research is aimed at describing an aspect of syntax of Kaninkon language. And our focus is negation in the language. Kaninkon is a language spoken in Jema’a local government area of Kaduna State, Nigeria. The native speakers call themselves kyung (Kaninkon). Although, the Kaninkon is not a major group in Nigeria, yet the speakers are found... Continue Reading
TABLE OF CONTENTS Title Page Certification Dedication Acknowledgement Abstract Table of Contents CHAPTER ONE: INTRODUCTION 1.1 General Background 1.2 Historical Background of Koenoem People 1.3 Geographical Location of Koenoem People 1.4 Socio-Cultural Profile of Koenoem People 1.5 Genetic Classification of Koenoem Language 1.6 Statement and... Continue Reading
GENERAL BACKGROUND This chapter will examine the general background of the study and described the speakers of the language in respect of their historical background and socio-cultural profile. It also, introduces us to the genetic classification of Kofyar, the scope and organization of the study together with the theoretical framework. The method... Continue Reading
ABSTRACT This study is a critical discourse analysis of negation in the inaugural speeches of two Nigerian Presidents. The study aims at finding out if negation performs certain statement. The data used for the analysis are from the speeches of the two Presidents, Goodluck Jonathan and Musa Yar’Adua. The speeches were adopted from different... Continue Reading